Lagos Yoruba Nation rally: Ìwádìí wa fihàn pé kìí ṣe òkú tútú ni ọmọ tí wọ́n sọ pé a pa ní Ojota – Ọlọ́pàá Eko
Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko ti fesi si iroyin to n lọ pe ọta ibọn wọn lo pa Jumoke, ọmọ ọdun mẹrinla ni Ojota l’Eko lasiko iwọde Yoruba Nation. Ninu atẹjade to fi sita, agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa naa, Muyiwa Odejobi sọ pe ayederu iroyin patapata ni iroyin naa, ati pe o jẹ ọna lati da ibẹru…
