Tinubu fi àmi ẹ̀yẹ MON dáwọn Super Eagles lọ́lá, ó tún fún wọn ni ilé àti ilẹ̀ l’Abuja
Yoruba bọ, wọn ni yinni yinni ki ẹni ṣe mii, eyi lo difa fun Aarẹ Bola Tinubu ti o fi ami ẹyẹ MON dawọn ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles lọla lẹyin ti wọn wọ ipele aṣekagba idije Afcon 2023 lorilẹede Ivory Coast. Bo tilẹ jẹ pe Ivory Coast to gbalejo idije naa gbo ewuro soju ikọ…