Home » Yoruba » Page 2

Oyo Covid-19 update, Delta variant of covid-19: Ó ṣeéṣe kí á kéde àwọn ìlànà tuntun láìpẹ́ – Ìjọba Oyo

Agbẹnusọ gomina ipinlẹ ọhun, Taiwo Adisa lo sọ bẹẹ ninu ifọrọwwerọ kan pẹlu BBC Yoruba. Adisa ni iwadii ijinlẹ ti awọn onimọ ipinlẹ naa ṣe lo tete jẹ ki awọn kofiri ẹda arun tuntun ọhun. Bo tilẹ jẹ pe o ni lootọ ni awọn ti fidi rẹ mulẹ pe ẹda arun naa tuntun ti ran…

Read More

Super TV CEO Ataga: Chidinma ò gbudọ̀ kú o sátìmọ́lé Ọlọ́pàá o! Àwọn aṣòfin f’ọ̀rọ̀ ráńṣẹ́ sí Ọ̀gá àgbà Ọlọ́pàá

Bakan naa, ile aṣojuṣofin tun ni ki wọn ṣe iwadii ati ayẹwo finifini lori ẹsun naa ki wọn si ma ṣafihan arabinrin Chidinma kiri mọ tabi ki wọn maa gbaa laye lati ba awọn oniroyin sọrọ lori ọrọ ti wọn ṣi n ṣewadii rẹ lọwọ. Ile aṣofin ni ki Ọga agba awọn ọlọpaa, Usman Baba…

Read More

Lagos Yoruba Nation rally: Ìwádìí wa fihàn pé kìí ṣe òkú tútú ni ọmọ tí wọ́n sọ pé a pa ní Ojota – Ọlọ́pàá Eko

Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko ti fesi si iroyin to n lọ pe ọta ibọn wọn lo pa Jumoke, ọmọ ọdun mẹrinla ni Ojota l’Eko lasiko iwọde Yoruba Nation. Ninu atẹjade to fi sita, agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa naa, Muyiwa Odejobi sọ pe ayederu iroyin patapata ni iroyin naa, ati pe o jẹ ọna lati da ibẹru…

Read More

Osun Masqurade attack: Kayode Esuleke, olórí egúngún to bá àwọn musulumi jà ní Osogbo wà láhámọ́ ọlọ́pàá

Rogbodiyan to waye laarin awọn ẹlẹsin musulumi ti ijọ Kamorudeen Society Central Mosque ati eleegun nilu Osogbo ni ọjọ Àìkú ti gba ọna miran yọ. Idi ni pe ileesẹ ọlọpaa ni ipinlẹ Ọṣun ti mu olori awọn eleegun naa, oloye Kayode Eṣuleke si ahamọ. Gẹgẹ bi iroyin abẹle kan ṣe sọ, ikọ ọtẹlẹmuyẹ fun ọga…

Read More