Home » Yoruba » Page 3

Wọn yan akọroyin Gbelegbọ awọọdu akọroyin to lami-laka fun ami-ẹyẹ YOMAFA ọdun yii

Awọn akọroyin Gbelegbọ meji, Taofik Afọlabi ati Kayọde Ọmọtọṣọ wa ninu awọn akọroyin ti wọn yan gẹgẹ bii akọroyin to lami-laka ju lọ fun ọdun 2020 ati 2021 fun ami-ẹyẹ YOMAFA.  Awọn akọroyin Gbelebọ yii wa ninu awọn oniroyin ti wọn lami-laka ti ajọ YOMAFA yan  fun ami-ẹyẹ akọroyin to dara ju lọ. Ọjọ kin…

Read More

Funmi Awelewa – N kò ní gbà kẹ lò mí tán, kẹ wá já mi jù sílẹ̀ bíi náírà márùn-ún àlòkù

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olólùfẹ́ Orijafunmi Awelewa, lọ tí ń janu lójú òpó Instagram láti gbé sẹ́yìn gbajúgbajà òṣèré olólùfẹ́ wọn, tó sọ̀kò ọ̀rọ̀ lu àwọn akẹ́gbẹ́ rẹ̀. Àwọn akẹẹgbẹ́ rẹ̀ yìí ló ní wọ́n fẹ́ràn láti má sanwó iṣẹ́ tí wọ́n bá bẹ akẹ́gbẹ́ wọ́n láti kópa nínú sinimá agbéléwò. Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe kọ́ soju…

Read More

Nigeria’sTwitter ban: Orílẹ̀-èdè Amẹrika pé kí Naijiria fòpin sí fifofinde Twitter.

Orílẹ̀-èdè Amẹrika tí bu ẹnu àtẹ́ lu bí ìjọba Nàìjíríà ṣe fòfinde lilo òpó ikansiraẹni Twitter tí wọ́n sì pàṣẹ láti fi ẹnikẹni tó bá ṣe bẹ́ẹ̀ jófin tó fi mọ́ àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn.Wọ́n ké sí ìjọba láti ṣe àtúngbéyèwò ìpinnu wọn. “Dídí àwọn ọmọ Nàìjíríà lọ́wọ́ láti kó ìròyìn jọ àti láti sọ…

Read More

June 12: Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá fàwọn èèyàn lọ́kàn balẹ̀ ṣáájú ìfẹ̀hónúhàn àyájọ́ ìjoba Arawak

Wamu wamu ni ileeṣẹ ọlọpaa duro ṣaaju iwọde tawọn eeyan kan n gbero lati ṣe lọjọ Abamẹta tii ṣe June 12. Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Osun, SP Yemisi Opalola lo fidi ọrọ yii mulẹ fun BBc Yoruba. ”Kiki ni awọn ọlọpaa wa bi ibọn fawọn to ba fẹ da rogbodiyan silẹ lọjọ June 12 nipinlẹ…

Read More