Home » Wọn yan akọroyin Gbelegbọ awọọdu akọroyin to lami-laka fun ami-ẹyẹ YOMAFA ọdun yii

Wọn yan akọroyin Gbelegbọ awọọdu akọroyin to lami-laka fun ami-ẹyẹ YOMAFA ọdun yii

Awọn akọroyin Gbelegbọ meji, Taofik Afọlabi ati Kayọde Ọmọtọṣọ wa ninu awọn akọroyin ti wọn yan gẹgẹ bii akọroyin to lami-laka ju lọ fun ọdun 2020 ati 2021 fun ami-ẹyẹ YOMAFA. 

Awọn akọroyin Gbelebọ yii wa ninu awọn oniroyin ti wọn lami-laka ti ajọ YOMAFA yan  fun ami-ẹyẹ akọroyin to dara ju lọ.

Ọjọ kin in ni osu kẹjọ, ọdun yii layẹyẹ ami-ẹyẹ naa yoo waye ni gbọngan ‘Ostra Hall’ to wa lopopona Jọbi Fẹlẹ, Ikẹja, nipinlẹ Eko. Olugbalejo ọjọ naa ni: Ọtunba Taiwo Afọlabi, nigba ti olugbalejo pataki yoo jẹ gomina ipinlẹ Eko, Ọgbẹni Babajide Sanwo_Olu.

Gẹgẹ bi atẹjade ti alakoso ati oludari ami-ẹyẹ naa,Ọtunba Gbenga Leo ṣe sọ, o ni ori erọ alatagba 

 lawọn eeyan yoo ti dibo fun ogunlogọ awọn eeyan ti wọn yan fun ami-ẹyẹ tọdun yii.    Bẹẹ lo sọ pe ko si ojusaju ninu ami-ẹyẹ, o ni ẹni ibo rẹ ba  pọju ni yoo gba ami-ẹyẹ naa.

Wọn yan akọroyin Gbelegbọ awọọdu akọroyin to lami-laka fun ami-ẹyẹ YOMAFA ọdun yii

Awọn akọroyin Gbelegbọ meji, Taofik Afọlabi ati Kayọde Ọmọtọṣọ wa ninu awọn akọroyin ti wọn yan gẹgẹ bii akọroyin to lami-laka ju lọ fun ọdun 2020 ati 2021 fun ami-ẹyẹ YOMAFA. 

Awọn akọroyin Gbelebọ yii wa ninu awọn oniroyin ti wọn lami-laka ti ajọ YOMAFA yan  fun ami-ẹyẹ akọroyin to dara ju lọ.

Ọjọ kin in ni osu kẹjọ, ọdun yii layẹyẹ ami-ẹyẹ naa yoo waye ni gbọngan ‘Ostra Hall’ to wa lopopona Jọbi Fẹlẹ, Ikẹja, nipinlẹ Eko. Olugbalejo ọjọ naa ni: Ọtunba Taiwo Afọlabi, nigba ti olugbalejo pataki yoo jẹ gomina ipinlẹ Eko, Ọgbẹni Babajide Sanwo_Olu.

Gẹgẹ bi atẹjade ti alakoso ati oludari ami-ẹyẹ naa,Ọtunba Gbenga Leo ṣe sọ, o ni ori erọ alatagba  eeyan yoo ti dibo fun ogunlogọ awọn eeyan ti wọn yan fun ami-ẹyẹ tọdun yii.    Bẹẹ lo sọ pe ko si ojusaju ninu ami-ẹyẹ, o ni ẹni ibo rẹ ba  pọju ni yoo gba ami-ẹyẹ naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *