
Oyo PDP: Ẹgbẹ́ alábùradà pín sí méjì, igun Kan ta kété sí Seyi Makinde
O dabi ẹni pe ipilẹ ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP, nipinlẹ Ọyọ ti n mì bayii, to si ṣe e ṣe ki ẹgbẹ naa o tuka, pin kelekele. Eyi KO ṣẹyin bi awọn agbaagba ẹgbẹ Kan ṣe kede pe, awọn ti da ẹgbẹ osẹlu naa si meji, abala Kan fun Gomina Seyi Makinde, ati…