
Mọ̀ nípa Bolaji Agbede ti Access Bank fi rọ́pò olóògbé Herbert Wigwe gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà tuntun
Ileeṣe Access Holdings Plc ti kede alakoso ati oludasilẹ agba tuntun fun ileeṣẹ naa lẹyin iku Herbert Wigwe to padanu ẹmi rẹ siluu Amẹrika. Ọjọ Aje, ọsẹ yii ni igbimọ awọn alakoso ileeṣẹ naa gbe ikede yii sita – ọjọ keji lẹyin iku Herbert Wigwe to jẹ alakoso tẹlẹ. Arabinrin Bọlaji Agbẹdẹ ni orukọ ẹni…