
wọn eeyan ilu Ajasẹ-Ipo rọ awọn afọbajẹ lati fi ẹni to yẹ sipo Olupo
Awon eeyan ilu Ajase-Ipo, nipinle Kwara ti ni ki awọn afọbajẹ ilu naa tete yan ẹni toyẹ sipo ọba ilu naa. Ninu ọrọ ti awọn eeyan kan ba wa sọ ni wọn ti sọ pe Omooba Taiwo Saliu Oniro Alebiosu lawon n fe gege bii oba tuntun niluu naa, wọn ni ọkunrin oniṣowo pataki naa…