
Ko sija mọ laaarin emi ati Saheed Oṣupa-Pasuma
Gbajumọ oṣere fuji nni, Alaaji Wasiu Alabi Ọdẹtọla Pasuma tawọn ololufẹẹ tun mọ si Ọga Nla fuji ti sọ pe ko ija tabi wahala kankan mọ laaarin oun ati gbajumọ oṣere fuji mi-in, Alaaji Saheed Oṣupa Akorede Okunọla ti wọn tun n pe Ọba Orin. Nibi ayẹyẹ kan to waye niluu Apapa- Ajẹgunlẹ ti Pasuma…