Trust Africa News

Massive investment in Railways game changer in maritime business – NPA MD

By Ephraims Sheyin Mr Mohammed Bello-Koko, Acting Managing Director of the Nigerian Ports Authority (NPA), has said that the massive investment that had revitalised the Nigerian Railway Corporation was a “game changer” in the maritime sector. “I must commend President Muhammadu Buhari for investing so much into reviving Railway transportation. It is really exciting that…

Read Full News

Buhari Oloto: Gbajúmọ̀ ọba tó lo sàá lágbo fàájì ìlú Eko fún ogójì ọdún ó le

Ebenezer Obey sọ pe iyalẹnu ni iroyin iku rẹ jẹ fun oun, to si ṣapejuwe rẹ gẹgẹ bi alatilẹhin oun timọtimọ fun ọpọlọpọ ọdun. Ọjọbọ ni iroyin iku Ọba Oloto, to tun jẹ gbajumọ nilu Eko, jade sita. Nigba aye rẹ, oun ni Ọba alaye ilẹ Iguru, Aguda, Surulere nipinlẹ Eko. Oṣu Kẹsan-an, ọdun 2020…

Read Full News

Radio Nigeria attack: Àwọn jàndùkú ba ọ̀kẹ́ àìmoye dúkìá jẹ́ lásìkò ìkọlù síAmuludun FM n’Ibadan

Ọkan lara awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ naa sọ fun BBC Yoruba pe ọpọ dukia ti iye rẹ ko din ni ọpọ miliọnu naira ni awọn janduku ọhun bajẹ lasiko ikọlu naa. Lara awọn ohun ti wọn bajẹ ni awọn irinṣẹ ti wọn n lo ni ọọfisi, awọn ferese ọọfisi, to fi mọ awọn ọkọ ayọkẹlẹ atawọn…

Read Full News

Hushpuppi news today: Wọ́n ní kí Kyari máá lọ ilé títí tí ìwádìí yóò fi parí lórí ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Hushpuppi.

Igbesẹ yii lo waye lẹyin ti ọga agba ileeṣẹ naa ni Naijiria, Baba Usman Alkali sọ pe ki wọn ṣe bẹẹ. Ninu atẹjade kan ti ileeṣẹ to n ri si ọrọ awọn ọlọpaa ni Naijiria, Nigeria Police Service Commision, fi lede, eyii ti agbẹnusọ rẹ, Ikechukwu Ani buwọlu, o ni ileeṣẹ naa ti pinnu pe…

Read Full News

Dangote Sugar records N131.9bn revenue in H1, cement posts N191.6bn in six months

Dangote Sugar Refinery has posted N131.95 billion revenue in its unaudited financial results for the half year (H1) ended June 30, 2021. The Group Managing Director/CEO of the refinery, Ravindra Singhvi, made the disclosure in a statement on Sunday. The company’s revenue rose by 27.8 per cent in contrast to N103.23 billion recorded in the…

Read Full News