Trust Africa News

Lagos Yoruba Nation rally: Ìwádìí wa fihàn pé kìí ṣe òkú tútú ni ọmọ tí wọ́n sọ pé a pa ní Ojota – Ọlọ́pàá Eko

Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko ti fesi si iroyin to n lọ pe ọta ibọn wọn lo pa Jumoke, ọmọ ọdun mẹrinla ni Ojota l’Eko lasiko iwọde Yoruba Nation. Ninu atẹjade to fi sita, agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa naa, Muyiwa Odejobi sọ pe ayederu iroyin patapata ni iroyin naa, ati pe o jẹ ọna lati da ibẹru…

Read Full News

Yoruba Nation: Ìrìn padà tẹ fún ìrìn, àwọn aláwo siwájú ìwọ́de láti kojú ọlọ́pàá l‘Eko

Iwọde Yoruba Nation Rally to kọkọ ṣebi ẹni pe ko ni waye nilu Eko ti pada gbera sọ bayi Ṣugbọn awọn ọlọpaa ati ọmọ ogun ti fi omi ati afẹfẹ tajutaju tu awọn oluwọde naa ka. Akọroyin wa to jabọ lati ibi iwọde naa nilu Eko sọ pe lọwọ aarọ ti oun debẹ niṣe lawọnb…

Read Full News